Godfidence Xtra expresses the authority we have in God. It makes us realize our identity in Christ.
Check out the artist page.
Stream all 1 songs for free.
Story behind the song
It was received in my dream. Inspired by God.
Lyrics
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Eni ba ti ni Jesu
_So ti ni?_
Ko ni lati jisoro
_So ti ni?_
Aya o le fo e mo
_So ti ni?_
To r'omo Baba ni e
_So ti ni?_
F'aye re fun Jesu
_So ti ni?_
F'aye re fun Jesu
_So ti ni?_
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Se o ti ni Jesu?
_So ti ni?_
Se o ti l'Oluwa?
_So ti ni?_
Ninu aye re?
_So ti ni?_
S'omo Baba ni e?
_So ti ni?_
Ara mi o lewu
_So ti ni?_
T'o baini Jesu
_So ti ni?_
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
BRIDGE:
?niti o joko ni ibi ìk?k? ?ga-ogo ni yio ma gbe ab? ojiji Olodumare.
Emi o wi fun ?l?run pe, Iw? li àbo ati odi mi; ?l?run mi, ?niti emi gb?k?le.
Nitõt? on o gbà mi ninu ik?kun aw?n p?y?p?y?, ati ninu àjakal?-àrun buburu.
Yio fi iy? r? bò mi, ab? iy?-apa r? ni emi o si gb?k?le: otit? r? ni yio ?e asà ati apata mi.
Emi kì yio b?ru nitori ?ru oru; tabi fun ?fa ti nfo li ?sán;
Tabi fun àjakal?-àrun ti nrìn kiri li okunkun, tabi fun iparun ti nrun-ni li ?sángangan.
?gb?run yio ?ubu li ?gb? mi, ati ?gbarun li apa ?tún mi: ?ugb?n kì yio sunm? ?d? mi
Kiki oju mi ni iw? o ma fi ri, ti o si ma fi wo ère aw?n enia buburu.
T'o ba ti ni Jesu
_So ti ni?_
Esu kan le ma hale
_So ti ni?_
Ko le bori re
_So ti ni?_
Eni to ngbenu re
_So ti ni?_
O ju taye lo
_So ti ni?_
Okan re a bale
_So ti ni?_
To ba ti ni Jesu
_So ti ni?_
Mo ti ni Jesu
_Mo ti ni_
Emi o jisoro
_Mo ti ni_
Aya o fo mi mo
_Mo ti ni_
Omo Baba ni mi
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_
Ara e ba mi yo
_Mo ti ni_