Song picture
Godfidence Xtra
Comment Share
License   $0.00
Free download
Godfidence Xtra expresses the authority we have in God. It makes us realize our identity in Christ.
Commercial uses of this track are NOT allowed.
Adaptations of this track are NOT allowed to be shared.
You must attribute the work in the manner specified by the artist.
Artist picture
Check out the artist page.
Stream all 1 songs for free.
Song Info
Genre
R&B Gospel
Charts
#1,103 today Peak #6
#91 in subgenre Peak #1
Author
Oluwabunmi Bamitale
Uploaded
December 26, 2022
Track Files
MP3
MP3 4.2 MB 128 kbps 4:34
Story behind the song
It was received in my dream. Inspired by God.
Lyrics
Mo ti ni Jesu _Mo ti ni_ Emi o jisoro _Mo ti ni_ Aya o fo mi mo _Mo ti ni_ Omo Baba ni mi _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ Eni ba ti ni Jesu _So ti ni?_ Ko ni lati jisoro _So ti ni?_ Aya o le fo e mo _So ti ni?_ To r'omo Baba ni e _So ti ni?_ F'aye re fun Jesu _So ti ni?_ F'aye re fun Jesu _So ti ni?_ Mo ti ni Jesu _Mo ti ni_ Emi o jisoro _Mo ti ni_ Aya o fo mi mo _Mo ti ni_ Omo Baba ni mi _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ Se o ti ni Jesu? _So ti ni?_ Se o ti l'Oluwa? _So ti ni?_ Ninu aye re? _So ti ni?_ S'omo Baba ni e? _So ti ni?_ Ara mi o lewu _So ti ni?_ T'o baini Jesu _So ti ni?_ Mo ti ni Jesu _Mo ti ni_ Emi o jisoro _Mo ti ni_ Aya o fo mi mo _Mo ti ni_ Omo Baba ni mi _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ BRIDGE: ?niti o joko ni ibi ìk?k? ?ga-ogo ni yio ma gbe ab? ojiji Olodumare. Emi o wi fun ?l?run pe, Iw? li àbo ati odi mi; ?l?run mi, ?niti emi gb?k?le. Nitõt? on o gbà mi ninu ik?kun aw?n p?y?p?y?, ati ninu àjakal?-àrun buburu. Yio fi iy? r? bò mi, ab? iy?-apa r? ni emi o si gb?k?le: otit? r? ni yio ?e asà ati apata mi. Emi kì yio b?ru nitori ?ru oru; tabi fun ?fa ti nfo li ?sán; Tabi fun àjakal?-àrun ti nrìn kiri li okunkun, tabi fun iparun ti nrun-ni li ?sángangan. ?gb?run yio ?ubu li ?gb? mi, ati ?gbarun li apa ?tún mi: ?ugb?n kì yio sunm? ?d? mi Kiki oju mi ni iw? o ma fi ri, ti o si ma fi wo ère aw?n enia buburu. T'o ba ti ni Jesu _So ti ni?_ Esu kan le ma hale _So ti ni?_ Ko le bori re _So ti ni?_ Eni to ngbenu re _So ti ni?_ O ju taye lo _So ti ni?_ Okan re a bale _So ti ni?_ To ba ti ni Jesu _So ti ni?_ Mo ti ni Jesu _Mo ti ni_ Emi o jisoro _Mo ti ni_ Aya o fo mi mo _Mo ti ni_ Omo Baba ni mi _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_ Ara e ba mi yo _Mo ti ni_
Song Likes
Comments
Please sign up or log in to post a comment.